OO TUN SE ALALUBOLE MO, O JE ASEGUN LOJOOJUMO
Iya afin Debora Lapido je wolii obirin, o si je adajo ni Isreali ti o se ohun ti awon obirin miran kose nigba bibeli. O gba Baraki niyanju lati gbogun ti awon ota aninilara ni ayika orile ede won, o si yan akikanju akoni bi asiwaju ogun won. Ni akoko na, won ko le doju ko ota won, nitori won kere si won niye. Baraki jewo iberu won ti o fi jewo pe ayafi ti wolii obirin Debora ba ma tele won, won ko ni doju ko ota won. Lati fun Isreali ni isegun, Debora gba lati tele Baraki lo si oju ogun bi o tile tako asa ati ise won.
Bibeli wipe Baraki si wi fun un pe ‘Bi iwo o ba ba mi lo, nje emi o lo sugbon bi iwo ki yoo ba mi lo, emi ki yoo lo. (Awon Onidajo 4:8) nitorina Debora tele Gideoni lo ja fun orile ede won won si segun (Awon Onidajo 4:23-24).
EKO
Onigbagbo ni lati mo ipo won pelu Olorun bi eni ti a ko le segun re, awa (Onigbagbo) ni emi. Olorun ninu wa, ki a si mo ara wa bi asegun ki a mo pe Olorun wa pelu wa, yi o si ma wa pelu wa lae lae. Anilati polongo agbara re nigba ipenija wa. Anilati kede iwa mimo tabi ijolotito re, bi enikeni ko se eyi. Eyi yi o mu ki Satani gbogun ni ona kona ti o ba gba, eyi yi o fun Olorun ni aye lati yin Oruko re logo. Eyi ni wipe Olorun yi o fara han ni akoko ipenija wa, lati jewo agbara re. kini a tun le so, se Olorun yi o ja won kule ni? Awon ti o wa ni ododo, Rara. Jehofa yi o gbeja oruko re, nitori na onigbagbo ni lati gbeke le Olorun, ki won si ma jewo ileri re ni gbogbo aye won.
ADURA
Olorun olufe jowo fun mi ni igboya nitoto lati ma so ti ododo re nigba gbogbo. Wo mi ni agbara nipase Emi Mimo, ki nle duro, gbigbe opa ododo ni wiwasu ihinrere. Fun mi ni igbagbo ti ko gbonjege si oun ti aye ati ife ti ese. mase je ki igbagbo mi gba ijakule ni akoko igbenija, sugbon je ki nma jeri ododo re titi un o fi bori, ni jijewo didara re. ni oruko Jesu Kristi ni mo beere. Amin.
