AGBODO WAASU IHINRERE
Awon Wolii Olorun so fun Paulu ki o mase polongo ihinrere re de Jerusalemu, won so fun pe a o se inunibini sii o si le yori si iku re. Sugbon Paulu tesiwaju bi won tile se ikilo fun to Paulu da awon agbani niyanju re lohun pe ‘Ewo ni eyin nse yi ti eyin unsunkun, ti e si nmu aare ba okan mi nitori emi mura tan, ki se fun didi nikan sugbon lati ku pelu ni Jerusalemu nitori oruko Jesu Oluwa, nigba ti a ko le paa ni okan da awa dake wipe, ife ti Oluwa ni ki a se.
(Awon Aposteli 21:13-14)
EKO
Olorun unfe oniwasu ti o fara jin ti yio gbe wiwasu laruge ju ohun yi o wu lo. Awon ojise ti won ni orisirisi ebun ati aisikii nilati se giri, ki won mokan le, ki won jade kuro ni agbegbe irorun, ki won waasu bo ti ye. Olorun ti seto pupo ore-ofe re ninu aye Okunrin ati obirin lati jade fun iwasu ita gbangba, o je dandan fun wa lati lo ohun ini wa lati gbe oruko Jesu Kristi ga. A ni lati lo gbogbo ohun elo boya kekere tabi titobi lati wasu ihinrere, ki a gbiyanju pe enikan ni Afrika gbo ihinrere, ojuse wa ni pe ki eni o sese de Asia di atunbi. Awon eniyan iwo-orun Amerika, ila-orun Amerika, Yuropu ati Oostralia ni lati fi aye won fun Jesu Kristi, awa iranse Oluwa ko ni lati dake a nilati ro awon eniyan ki won le gba Jesu Kristi ni Oluwa ati Olugbala won, ki won ba le wo ijoba Olorun.
ADURA
Olorun mo feje Kristieni ti kin beru lati wasu ihinrere ni gbogbo ona, mo pinu mo si setan lati wasu emi yi o se eyi niwon igba ti mo ba ni ore-ofe re, mo fe lo ebun ati ohun ini mi fun mimu eniyan wa sodo Jesu Kristi laisi awawi tabi ikunsinu, je ki nlo awon anfani ti mo ni, ki o si tun fun mi ni tuntun miran. Je ki unle lo ebun ere oritage, orin kiko, oro siso, ero-igbalode ati awon ohun miran lati le fi fa okan awon eniyan wa sinu ijoba re, ni opin ohun gbogbo je kin wo orun kin gbo ohun oro re pe ‘Kaabo ojise mi ti o dara. Ni oruko Jesu Kristi ni mo beere. Amin.
