image

MA SE FI OJU DI OLORUN; O LAGBARA LORI OHUN GBOGBO

Oba Siria ati awon Omo ogun re foju di Olorun, won yepere abo Olorun. Nigba ti awon Olorun kekeke (orisa) ti ja awon Sir

Read More
image

AIGBORAN A MAA JASI IJIYA

Oba Ahabu ni aafin ti o tobi, sugbon o jowu Naboti ti o ni ogba kekere. Oba oloju kokoro yi, gbimo papo pelu iyawo re (J

Read More
image

B’OWO FUN AWON ENI IFAMI ORORO YAN OLORUN

Paulu ati Barnaba fi oye ye awon eniyan ti o nfiyin fun won, ki won mase yin eniyan, bikose Olorun. Nigbati Paulu waasu

Read More
image

OLORUN WA KO SE N BA FIGAGBAGA

Woli Elija fi han ijolooto re si Olorun han, o si doju ti awon Alagabagege. Woli yi penija awon olori ogun, bi oun ko ti

Read More
image

E MA SE JE OLUGBO NIKAN

O ye ki awa Kristeni ki a ka, ki a si teti gbo oro Olorun, ki a si mu won lo, ninu isesi igbe aye wa. Won ro wa lati lo

Read More
image

IHINRERE KO SE N DADURO

Awon ota ihinrere pa Stefanu nitori igbagbo re ninu Jesu Kristi. Won so o ni okuta titi o fi ku, saaju iku re Stefanu lo

Read More
image

SO AHON RE, SO ORO ENU RE

O je ese ki a se ojusaju si eniyan. Olorun nfe ki awon omo re yera fun eleya meya, ki a si se bakan naa si gbogbo eniyan

Read More
image

FI IGBEKELE SINU AGBARA ABO OLORUN

Olorun damu oba saulu, ko je ki o segun Dafidi. Bibeli wipe, sauli si nrin ni apakan oke kan, Dafidi ati awon omokunrin

Read More
image

A KO LE GAN OLORUN

Judasi iskariotu yonda ara re fun satani lati loo, o si fi Jesu Kristi han pelu ifenu ko enu. A kowe re pe bi o ti nso l

Read More
image

ISIN OLORUN KEKEKE O LODI SI OLORUN

Oba kan ti a npe ni Jehu gbe igbese akoni lati ja fun awon omo Israeli ti o si te Olorunlorun. O gbe ese ibinu re sori i

Read More