OO KIN SE ENIYAN LASAN
Nehemiah se aseyori nipa atunko odi Jerusalemu pelu awon eniyan re (Israeli) loju idojuko lati odo Sanballati ati Tobaya. Eniyan Olorun ati awon eniyan re se aseyori, won si yo ayo aseyege won. Bibeli wipe ‘ati nigba yiya odi Jerusalemu si mimo, won wa awon omo lefi kiri ninu gbogbo ibugbe awon lati mu won wa si Jerusalemu lati fi ayo se iyasi mimo naa pelu idupe ati orin, pelu Simbali, Psalteri, ati pelu duru (Neheiah 12:27).
EKO
Ko si ohun ti ko ni seese fun Kristeni ti o ba pinnu lati sin Olorun pelu otito. Jehofa yi o se atilehin fun won loju idojuko won, yi o ran wo lowo lati se aseyori. O se Pataki ki onigbagbo mo pe a kii se, eniyan lasa. Awa je eni ifami ororo yan. Olorun lati se aseyori ninu aye. Olorun wa nipa odo wa, yi o ran wa lowo lati se aseyori ni gbogbo ona wa. Ko ni si koseese kan fun eni ti igbekele re ba wa ninu Olorun.
ADURA
Olorun olufe, je ki emi mo ipo mi gege bi omo Olorun, ti a bi lati se aseyori ninu aye. Ran mi lowo lati gbe igbese igbagbo lati se ise nla fun o. Bukun ise mi, ki emi lee jeeri didara re laarin awon eniyan ti o yi mi ka. Jowo je ki eri didara re si mi, ki o wa titi laelae. Ni oruko Jesu Kristi ni mo beere. Amin.
