OLORUN YIO GBA ENIKENI TI O YI PADA SI
Awon Juu ti a ko ni igbekun pada si Jerusalemu (ilu ibile wa) se atunse majemu won pelu Olorun won seleri lati tele ofin Olorun nipa eto igbeyawo won si seleri lati pa ofin ojo isimi mo. Awon eniyan wipe, ‘bi awon eniyan ile naa ba mu ojo tabili ohun jije wa ni ojo isinmi lati ta, awa ki yoo raa ni owo won ni ojo isimi, tabi ni ojo mimo, awa o si fi odun keje sile, ati ifi-agbara gba gbese
EKO
Olorun nfe lati sise pelu Kristeni ti o ba pinnu lati sin Olorun dara. Yi o si ba Kristeni to ba ronupiwada sise papo. Jehofa yi o gbaa pada, apehinda ti o ba ronupiwada gege bi omo oninan kunan ninu bibeli. (Luku 15:11-32). Enikeni ti o ba ronupiwada ese re ti o si sin Olorun daradara, a ko ni daa lebi ni ojo idajo Olorun. Eni naa yi o ni ibugbe pelu Olorun ni orun rere.
ADURA
Olorun olufe, jowo fun mi ni okan ti o tele ilana re. Ran mi lowo lati ronupiwada ese mi, ki emi di eda titun ki emi lee yege fun ijoba re. Darijimi awon ese mi to ti koja, ki emi le bere sinni maa gbe igbe aye iwa mimo niwaju re. Je ki ona mi te o lorun nile aye, ki emi le yege fun ijoba ayeraye re. Ni oruko Jesu Kristi ni mo beere Amin.
