OLORUN N FI OKAN TO O
Ayaba Esteri lo ipo re lati gbaa awon Juu la lowo ogbeni Hamani ti o pinu lati pa won run. Mordekai lo ta ara sodo Esteri. O wi fun ki o lo anfani ti Olorun fun, ti kowopo lati gba awon eniyan re la. Mordekai kilo fun Esteri ki o masekuna. O wipe nitori bi iwoba pa enu re mo patapata ni akoko yii, nigba naa ni iranlowo ati igbala awon juu yoo dide latii bomi ranwa, sugbon iwo ati ile baba re ni a o parun, tani o simo bi nitori iru akoko bayi ni iwo se de ijoba? (Esteri 4:14)
EKO
Kristeni ni lati ranti lati ma bu ola fun Olorun pelu ipo won nitoriti o ka won ye. Gege bi iranse ti o see gbekele, awa (onigbagbo) ni lati sa gbogbo ipa wa lati lee te Olorun lorun. Inu Eledayi o dun lati rii wipe a ko jaakule nitori yi o bukun wapada. O nii iparo fun alaigboran omo, yi o yo omoti o ba seaigboran kuroyi o si fi eyiti o ba dararopo re. Nitorinaa gbogbo Kristeni ni lati bu ola ti o ye fun Olorun ki a sisin-in pelu gbogbo okan ti okun wa.
ADURA
Olorun olufe jowo ran mi lowo lati sin o, ki emi si bowo to to fun o. Mase je ki emi o fin kiun, ma se siipo anfani mi lo. Ran mi lowo lati lee lo ore-ore Olorun fun itesiwaju iyin logo oruko re ni gbogbo aye mi. Jowo mase je ki emi ja o kule, ki emi lee ye fun ibukun re ni gbogbo igba. Ni orukoJesu Kristi ni mo beere. Amin.
