Bibeli atoka dara fun kika oro Olorun. Paulu iranse Olorun gba awon Kristeni niyanju lati duro ninu otito igbagbo.
Bible Combo wa gege bi bibeli atoka ni ede yoruba fun awon omo Olorun. Eyi se pataki ni tori kiwon mase ko asa ti ko se anfani fun ijoba Olorun.
Kika Bibeli ede Yoruba dura fun awon omo eyin Kristi ti o je omo Yoruba kaa kiri no gbogbo agbaye.
Paulu wipe ‘Nitori naa e ma se je ki enikeni maa se idajo yin ni ti jije, tabi ni ti mimu, tabi ni ti ojo ase, tabi osu titun, tabi ojo isimi. Awon tii se ojiji ohun ti nbo, sugbon ti Kristi ni ara. E ma se je ki enikeni fi adabowo irele ati bibo awon angeli lo ere yin gba lowo yin, eni ti n duro lori nnkan won-on-ni ti o ti ri, ti o n ti ipa ero re ni ti ara sefefe ara. Ti ko si di ori nni mu sinsin, lati odo eni ti a n ti ipa orikee ati isan pese fun gbogbo ara, ti a si n soo sokan po, ti o si ndagba nipa ibisi Olorun. Bi eyin ba ti ku pelu Kristi kuro ninu ipilese aye eeha ti se ti eyin nteriba fun ofin bi eni pe eyin wa ninu aye. Ma se fowokan, ma se towo, ma se fowobo. (Kolose 2:16-21)
Bibeli mimo ni ede Yoruba wa fun igbiyan ju ninu oro Olorun. Kristeni ni lati kiyesara nipa ohun ironu ti aye, sugbon ki o duro lori awon oro Olorun. Ki a mu iduro wa ninu Olorun, ki a ko gbogbo ikoni ti ko fese mule ninu Bibeli. Ki a kiyesara ki Satani mase tan wa lo sinu gbigba iran eke gbo. Ki a mase gba ni aye, iran, eko tabi imoran ti o tako Bibeli. Ki a fowo sowo papo pelu Emi-Mimo lati dari wa ninu otito. Ki a fun un (Emi Mimo) ni aye, ki o pese wa fun ere oro ni ile aye yi, ati ni orun pelu.
Awon ona ti a le gba mo ife Olorun po, sugbon ko si okan kan ninu won ti o dabi kika oro Olorun.
Ale ka bibeli english, bibeli orin dafidi, bibeli yoruba kjv, ese bibeli fun adura, ese bibeli fun adura anu, iwe owe bibeli, awon eko bibeli, eko bibeli ni ede yoruba, eko bibeli yoruba, eko ninu bibeli, eko nipa bibeli
E maa ka oro Olorun ki e si maa se asayan ninu oro re ni ojojumo.
Aanu Olorun Eledumare ki o maa ba gbogbo wa gbe lai at lai lai. Amin.
Do you know a different language other than English? Register now and start to translate our devotions. May God reward your effort!
Subscribe for our newsletter